The content is just an excerpt from the complete note from Yoruba Lesson Note from SS1 – SS3. Check below for the appropriate link
ODUN IGBEKO YORUBA – SS 1
ISE OOJO-SAA KIN-IN-NI
OSE KIN-IN-NI
EKA ISE: EDE
AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA – IFO (EYA ARA ISORO)
Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade
A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni;
AWON EYA ARA TI A FI N PE IRO EDE
AFIPE: Afipe ni gbogbo eya ara ifo ti won kopa ninu pipe iro ede jede. A le pin awon afipe wonyi si meji; awon nii
Ipo ti ahon ati ete wa ninu pipe faweli ede Yoruba
A le pin ahon si isori meta ninu pipe iro jade. Awon ni;
Faweli perese: Eyi ni faweli ti a gbe jade nigba ti ete fe seyin ti alafo gigun tin-in-rin wa laarin ete memeeji. Awon faweli naa ni, a,e,e,I,an,en,in.
Faweli roboto: Eyi ni awon faweli ti a gba jade nigba ti ete ka roboto. Awon ni, o,u,o,un,on.
EKA ISE: ASA
AKOLE ISE: EKO ILE- ASA IKINI
Eko ile ni eko iwa hihu: iwa rere, iwa to to, iwa to ye ti obi fi n ko omo lati kekere.
Eko ile je iwa omoluabi, ati kekere ni iru eko yii ti n bere ti yoo si di baraku fun omo titi ojo aye re.
Dandan ni fun omo lati mo bi ati n ki baba, iya ati awon miran ti o ju ni lo ni gbogbo igba.
Ikini akoko / igba.
IGBA / AKOKO | IKINI | |
I | Ojo | Eku ojo / otutu |
Ii | Oye | Eku oye |
Iii | Iyan | Eku aheje kiri o |
Iv | Ni owuro | Ekaa oro |
V | Ni osan | Ekaa san |
Vi | Ni irole | Eeku irole |
Vii | Ni oru | Ekuaajin |
Ikini akoko Ise
ISE | IKINI | IDAHUN | |
I | Agbe | Aroko bodu de o | Ase |
Ii | Onidiri | Oju gbooro, eku ewa | Iyemoja |
Iii | Babalawo | Aboru boye, sboye bo sise | Amin |
Iv | Awako | Oko a re foo, goun a pana mo o | Amin o |
V | Akope | Igba a ro o | O o |
Vi | Osise ijoba | Oko oba ko ni sa yin lese | Ase |
Viii | Iya oloja | Aje a wo gba o | Ase |
EKA ISE: LITIRESO
AKOLE ISE: ATUYEWO ORISIRISI EYA LITIRESO
Litireso ni akojopo ti a fi oro ni ede kan tabi ti e ko sile.
Isori litireso
Litireso alohun: Eyi ni awon ewi ti a jogun lati enu awonn babanla wa.
Ohun enu ni a fi n gbe litireso jade, ko si ni akosile rara.
Litireso alohun kun fun o gbon imo ati oye agba, nigba ti imo moo ko moo-ke ko ti de ile wa ohun ni awon baba nla wa n lo ninu igbo ke gbodo won.
Litireso alohun pin si ona meta
DOWNLOAD Complete note for SS1 FIRST TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS1 SECOND TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS1 THIRD TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS2 FIRST TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS2 SECOND TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS2 THIRD TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS3 FIRST TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS3 SECOND TERM >> LINK
YORUBA LANGUAGE SS ONE
ETO ISE FUN SAA KEJI
Ose kin-in-ni Ede-Atunyewo awon isori oro ninu ede Yoruba
Asa:Elegbejegbe tabi iro-siro
Litireso: Itupale iwe aseyan ti an ka
Osa keji Ede-Awon isori gbolohun ede Yoruba gege bi ihun
Asa: Asa iranra-eni lowo
Litireso: kika iwe litireso ti ijoba yan
Ose keta Awon isori gbolohun Yoruba gege gi ise won
Asa: Itesiwaju ninu asa iranra-eni lowo
Litireso : kike iwe litireso ti ijoba yan
Ose kerin Ede-Aroko asapejuwe (ilana)
Asa: oge sise(1)
Litireso: kika iwe litireso ti ijoba yan
Ose karun-un Ede- Akanlo ede
Asa : oge sise (2)
Litireso : kika iwe litireso ti ijoba yan
Ose kefa Ede- sise aayan ogbufo
Asa: Igbeyawo ibile
Litireso: Kika we litireso ti ijoba yan
Ose keje Ede-sise aayan ogbufo
Asa: igbeyawo ni ile Yoruba, orisi igbeyawo ti o wa
Litireso: kika iwe litireso apileko ti ijoba yan
Ose kejo Ede-onka ede Yoruba ookan de egbaa (1-2000)
Asa: Asa igbeyawo
Litireso: kika iwe litireso ti ijoba yan
Ose kesan Ede- Atunye eko lori
Asa: Oyun ninu, itoju ati omo bibi
Litireso : Itan oloro geere bii; orisunn itan ati asa Yoruba
Ose kewaa Ede- Aroko asotan oniriyin
Asa: Asa isomoloruko
Litireso: Alo apamo ati apagbe
Ose kokonla agbeyawo ise saa keji
Ose kejila Idanwo Ipari saa keji
Ose kin-in-ni
Akole ise: Ede- Atunyewo
Isori oro ninu ede Yoruba
Isori oro ninu ede Yoruba ni wonyii
Oro-oruko: Eyi ni awon oro ti won le da duro ni ipo Oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun.
Ipo meta ni oro oruko le ti jeyo ninu gbolohun. Awon ni ;
Sola lo si iwo
Ade jeun yo
Alaafia to oyo
Oluko ra oko ni ona
Jide gun iyan
DOWNLOAD Complete note for SS1 FIRST TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS1 SECOND TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS1 THIRD TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS2 FIRST TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS2 SECOND TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS2 THIRD TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS3 FIRST TERM >> LINK
DOWNLOAD Complete note for SS3 SECOND TERM >> LINK
Veterinary medicine is the branch of medicine that deals with the prevention, diagnosis, and treatment…
Anthropology is the scientific study of human beings and their cultures. It encompasses a wide…
Sociology is the scientific study of human society, culture, and behavior. It examines the social…
Social Work is a profession dedicated to helping individuals, families, and communities to cope with…
Religious studies is an academic discipline that explores the beliefs, practices, and history of various…
Public administration is the field of study and practice that focuses on the organization and…